Gospel talent music act, Kenny Micstyle releases a new song titled “Oda Pe”
The song is a song of praise, Our God is glorious.

Our God is Great God, He is mighty in all his ways, He is an awesome God, Arogun gbogunmi ogbeje
Ensure to download, Listen and share.
You will definitely be blessed

Listen and Download on AudionMack

Download Here

Lyrics: Oda Pe by Kenny Micstyle
Speaking in tongues
Arogun gbogunmi ogbeje x4
Olorun mi da ape
Olorun mi da ayepe
Osubare re o baba
Mope lakoda aye ooo
Ohun laseda orun
Olorun gbogbo eran ara
Alejo ton mi onile tititi
Alejo ton le onile lori ibusu tonile ko ni aye oto asima joba nibe
Alejo ton wa ohun tonile Oje kiri
Ko seni toti daye nigba totin joba ooo
Koseni tole dupo oba mo o lowo
Odagba titi olewu lori
Ejoba titi aye
Ejoba lajule orun
Ejoba ninu iho ile
Kinihun oba eranko nteriba forukore lasan
Airi ninu riri
Riri ninu gbigbo
Ejoba oluwa,
Oda ayepe
Oda orun pe
Ite aga re nbe lorun
Eni tin je eledumaaaaaaaaare
Sangiri
Lagiri
Arogun gbogunmi ogbe je X4
Odape__shout
Odape__scream
Odape __sing
Odape oooo
Odape X4
Odape oooo
Ase ninu aye
Ase lajule orun
Arokeke lalakeji
[10/13, 12:19 AM] Kenny: Olotu orun
Oniso iboji
Ogbamugbamu oju orun ose gbam I
Idagbodagbo oju orun ose dagbosi
Ikobe kola oju orun ose kolasi
Ajulo awon orisa
Alagogo iyanu
Iwadi aimo
Opa orokun
Alaga iwofa
Oba oluponmi sapere dojuti doro
Kakaki oro
Sunukun oro
Abaso fele tenikan oleka
Efufulele timigbo kijikiji
Obamifirigbon gbogun esu wole ooooo
Odape eee
Odape X4
Speaking in tongue
Eniton gbani ton Lani
Omoni onseni
Onfuni otungba
Eeeeee
Onfuni otungba
Eledumare lefun oooo
Kotungba lowo re
Eyin toba fun e mofe ko loo
Onfuni otungba
Obanirin ki iya tan oooo
Can you shout

Contact Kenny
Instagram: @Kenny_micstyle

0 Shares

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here