Super Gospel music Minister, Tope Adeniyi releases a new song titled Onike Anu.

Speaking About the song, she said..
What God cannot do does not exist, it’s not that God cannot do all that we wanted, but His thought is quite different from our thought. He gives special care of mercy to us all.

Tope Adeniyi is a fast-rising gospel ministrel who hails from Ondo state. A University graduate. Happily married with children. She has been a choir coordinator since 2003 till date. A songwriter who has written/composed some great songs such as Rccg Lagos Province 51 monthly programme theme song, RCCG Region 2 Anthem, God of Adeboye, Oruko nla, Onike Anu Oluwa Onise Iyanu, Mo mu ope wa among other spirit lifting tracks in her album

Click below to Listen and Download Song

Lyrics
Olorun gbogbo nise ni O(2ce
On to ni lese ko i ti daye oo
Eyi ti waa bere to o ni lee pari ko i ti de.
Ise to o le se to o ni se Iyen po laye jojo,
kii se pe OO lee se
Ero Re lo ya to si tiwa, Ise aye atorun ikawo Re lowa,
Oba to mo ohun gbogbo
Ninu ohun gbogbo
To si le se ohun gbogbo, eee.
Olorun gbogbonise ni O

O oooo ooo ooo
E ba mi ki o
Ki n gbo o

Res – Onike Anu

A aaaa aaa aaaa
E ba mi ki oo
Ki n gbo o

Res – Onike Anu

Onike Anu mi ni O(2ce
Ike ti mo ri gba lodo Re lati inu ole
Bi ko ba si Ike Re,
oju iba ti mi oo
E seun mi oo
Onike anu

Chr. Onike anu mi oo
Onike anu. (2ce
Bi ko si Ike Re
Mba deni yeye o
E seun mi o
Onike Anu

Alaanu mi ni O
Iwo lo n saanu fun mi lojo ogun le ati lojoojo
Anu ti mo ri gba lodo Re,
Gbe yeye aye fo mi da o mo dupe temi o
Alaanu mi
E se oloore

Chr Onike Anu

Atinileyin mama ti ni loju
Iwo lo n ti mi leyin lati igba ewe mi wa
Ninu hila hilo ayee
O moomo ye
O moomo dagba
Atinileyin yi o
E mama seun,
Atileyin ma doju tini

Chr ; repeat

Oniduro, onigbowo o olutojuoo alatileyin mi

Jesu Oniduro
Kristi onigbowo o
Eyin naa lolu toju ati alatileyin mi

Lati ila oorun de Iwo oorun,
Lati Gusu de Ariwa,
La O ma gboruko Re ga
Olorun mimo, ogo ye O
Olorun ti ko seun ti
Mobola fun O
Kabiesi Re o
Oba aterere kaye atorun o,
O mi aye morun tititi korun ataye dake jeje niwaju Re
Okun ri O, o sa, Jordani ri O, o pada seyin, oke nla nfo bi agbo oke kekeke won o le duro, niwaju Re

Response: Oniduro, onigbowo…..

topeadeniyielyuba@gmail.com
FacebkTope Adeniyi El-Yuba
Inst topeadeniyielyuba

0 Shares

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here